ADARIJI ATI IDONUPIWADA
1.
Idariji
eche lantoro {bis}
Baba
mimo, omo mimo
Kowa
dari re jiwa
2.
Anu
re lawa ntoro {bis}
Baba
mimo omo mimo
Kowa
ranu re si wa
3.
Iwosan
re la ntoro {bis}
Baba mimo, omo mimo
Kowa ran wosan si wa.
4.
Igbala rela ntoro {bis}
Baba mimo, omo mimo
Mowa fi gbala fun wa.
5.
Ibukun rela ntore {bis}
Baba mimo, omo mimo
Kowa
ran bukun si wa.
6.
Igbala
kela ntoro {bis}
Baba
mimo, omo mimo
Kowa run gbeba si wa.
7.
Ako lowa la ntoro
Baba mimo, omo mimo
Mowa dabo le bawa
16/12/2009
Retour aux articles de la catégorie Cantiques célestes -
⨯
Inscrivez-vous au blog
Soyez prévenu par email des prochaines mises à jour
Rejoignez les 35 autres membres