ADURA
Adura
l’ope ise gun l’oni gbagbo
Ipele
rere ti JESUS o ma l’adura
Adura
yi oni JESUS ma ma n’kowa
Adura
l’ebo oni gbagbo t’a ofi segun.
Ara ye ema bo wa ka gbadura
Ibere kosi JEHOVAH wa m’be
l’aye
S’ati gbagbo ope JESUS yà gbe
dura re
Adura le bo oni gbagbo t’a ofi
segun.
Adura
o egba dura
Gbadura
o oni gbagbo
Ka
ba le segun o
Gbogbo
ta l’aye o egbadura.
Bile
aye yi ba le sake p’oluwa
Ma
beru o JEHOVAH yo o d'a l'ohun
ASIKO YIO GBA JESUS-CHRIST
ni oba
Orisa re to n’sin kole gba
ola.
Tete wa k’owa mo JESUS ni
oba
Aiko igi bibo ofi k’ola o
Tete
gbagbo o wa JESUS n’gba te le ri
Oko
iyawo fere de l’ogan jo orun.
Amen.