EMI MIMO OLUTUNU
1.
Emi
mimo olutunu
Sokale
sarin wa
Ire
l’Oba olubuku
Awa
n’se reti re.
2.
Nitoripe
irel’Oba
N’la
Oba olore
Oba
emi sokale wa
Awa
n’se reti re.
3.
Oba
anu sokale wa
Si
ju anu wo wo
Awa
omo re n’wo jure
Si
le kun anu re
4.
oba
mimo Oba olore
Baba
jo bukun wa
Nitoripe
ire l’Oba
Tio
oukun omo re
5.
Oba
anu oba iye
Tan
mole re fun wa
Ire
l’Oba kiki mole
Awa
n’se reti re
6.
Oba
mimo oba iye
Jowo
wa bukun wa
Nitoripe
re l’Oba anu
Awa
n’se reti re
7.
Emi
mimo emi olore
Awa
n’se reti re
Oba
mimo sokale wa
Wa
gunwa sarin wa
Amen.